Iranse ni orin ati oro Olorun. Mak 16:15 YCE - O si wi fun wọn pe, Ẹ lọ si gbogbo aiye, ki ẹ si wasu ihinrere fun gbogbo ẹda. Iran wa nibi ChristlikeRadio ni lati tan ORO OLORUN si iran yi lati fun araye ni iyanju ninu igbe aye mimo lati je ki a mo pe Kristi ni, yoo si maa wa ati pe yoo pada wa.
Awọn asọye (0)