Agidigbo 88.7 jẹ ile-iṣẹ redio iṣowo akọkọ ti orilẹ-ede Naijiria ti o n dapọ mọ iṣẹ-igbohunsafefe iwa pẹlu itara kaakiri. A fi idi re mule lati tun eto igbesafefe pada sipo ni ilu Ibadan, ipinle Oyo ati ni gbogbo orile ede Naijiria nipa fifi ayo awon araalu se pataki ninu gbogbo ohun ti a ba n se, idi ni yii ti won fi n pe wa ni 'Ohùn Eniyan'.
Awọn asọye (0)